Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 13:59 Yorùbá Bibeli (YCE)

Eyi li ofin àrun ẹ̀tẹ, ninu aṣọ, kubusu tabi ti ọ̀gbọ, iba ṣe ni ita, tabi ni iwun, tabi ohunkohun èlo awọ kan, lati pè e ni mimọ́, tabi lati pè e li aimọ́.

Ka pipe ipin Lef 13

Wo Lef 13:59 ni o tọ