Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 13:55 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki alufa ki o si wò àrun na, lẹhin igbati a fọ̀ ọ tán: si kiyesi i, bi àrun na kò ba pa awọ rẹ̀ dà, ti àrun na kò si ràn si i, alaimọ́ ni; ninu iná ni ki iwọ ki o sun u; o kẹ̀ ninu, iba gbo ninu tabi lode.

Ka pipe ipin Lef 13

Wo Lef 13:55 ni o tọ