Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 13:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi àmi didán na ba funfun li awọ ara rẹ̀, ati li oju rẹ̀ ti kò si jìn jù awọ lọ, ti irun rẹ̀ kò di funfun, nigbana ni ki alufa ki o sé alarun na mọ́ ni ijọ́ meje:

Ka pipe ipin Lef 13

Wo Lef 13:4 ni o tọ