Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 13:26 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn bi alufa ba wò o, si kiyesi i, ti kò sí irun funfun li apá didán na, ti kò si jìn jù awọ ara iyokù lọ, ṣugbọn ti o ṣe bi ẹni ṣújú; nigbana ni ki alufa ki o sé e mọ́ ni ijọ́ meje:

Ka pipe ipin Lef 13

Wo Lef 13:26 ni o tọ