Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 10:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati igẹ̀ fifì, ati itan agbesọsoke ni ki ẹnyin ki o jẹ ni ibi mimọ́ kan; iwọ, ati awọn ọmọkunrin rẹ, ati awọn ọmọbinrin rẹ pẹlu rẹ: nitoripe ipín tirẹ ni, ati ipín awọn ọmọ rẹ, ti a fi fun nyin ninu ẹbọ alafia awọn ọmọ Israeli.

Ka pipe ipin Lef 10

Wo Lef 10:14 ni o tọ