Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 10:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Mose si wi fun Aaroni, ati fun Eleasari ati fun Itamari, awọn ọmọ rẹ̀ ti o kù pe, Ẹ mú ẹbọ ohunjijẹ ti o kù ninu ẹbọ OLUWA, ti a fi iná ṣe, ki ẹ si jẹ ẹ lainí iwukàra lẹba pẹpẹ: nitoripe mimọ́ julọ ni:

Ka pipe ipin Lef 10

Wo Lef 10:12 ni o tọ