Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 10:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

ATI Nadabu ati Abihu, awọn ọmọ Aaroni, olukuluku nwọn mú awo-turari rẹ̀, nwọn si fi iná sinu wọn, nwọn si fi turari sori wọn, nwọn si mú ajeji iná wá siwaju OLUWA, ti on kò fi aṣẹ fun wọn.

Ka pipe ipin Lef 10

Wo Lef 10:1 ni o tọ