Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 1:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi ọrẹ-ẹbọ rẹ̀ ba ṣe ẹbọ sisun ti inu ọwọ́-ẹran, ki on ki o mú akọ wá alailabùku: ki o mú u wá tinutinu rẹ̀ si ẹnu-ọ̀na agọ́ ajọ siwaju OLUWA.

Ka pipe ipin Lef 1

Wo Lef 1:3 ni o tọ