Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 1:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi o ba si ṣepe ti ẹiyẹ ni ẹbọ sisun ọrẹ-ẹbọ rẹ̀ si OLUWA, njẹ ki o mú ọrẹ-ẹbọ rẹ̀ wá ninu àdaba, tabi ninu ọmọ ẹiyẹle.

Ka pipe ipin Lef 1

Wo Lef 1:14 ni o tọ