Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jon 1:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina nwọn kigbe si Oluwa nwọn si wi pe, Awa bẹ̀ ọ, Oluwa awa bẹ̀ ọ, máṣe jẹ ki awa ṣegbe nitori ẹmi ọkunrin yi, má si ka ẹjẹ alaiṣẹ si wa li ọrùn: nitori iwọ, Oluwa, ti ṣe bi o ti wù ọ.

Ka pipe ipin Jon 1

Wo Jon 1:14 ni o tọ