Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joel 3:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Yio si ṣe li ọjọ na, awọn oke-nla yio ma kán ọti-waini titún silẹ, awọn oke kékèké yio ma ṣàn fun warà, ati gbogbo odò Juda yio ma ṣan fun omi, orisun kan yio si jade lati inu ile Oluwa wá, yio si rin afonifojì Ṣittimu.

Ka pipe ipin Joel 3

Wo Joel 3:18 ni o tọ