Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joel 2:26 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹnyin o si jẹun li ọ̀pọlọpọ, ẹ o si yó, ẹ o si yìn orukọ Oluwa Ọlọrun nyin, ẹniti o fi iyanu ba nyin lò; oju kì o si tì awọn enia mi lai.

Ka pipe ipin Joel 2

Wo Joel 2:26 ni o tọ