Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joel 2:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn emi o ṣi ogun ariwa nì jinà rére kuro lọdọ nyin, emi o si le e lọ si ilẹ ti o ṣá, ti o si di ahoro, pẹlu oju rẹ̀ si okun ila-õrun, ati ẹhìn rẹ̀ si ipẹkùn okun, õrùn rẹ̀ yio si goke, õrùn buburu rẹ̀ yio si goke, nitoriti o ti ṣe ohun nla.

Ka pipe ipin Joel 2

Wo Joel 2:20 ni o tọ