Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Job 39:29-30 Yorùbá Bibeli (YCE)

29. Lati ibẹ lọ ni ima wá ọdẹ kiri, oju rẹ̀ si riran li òkere rere.

30. Awọn ọmọ rẹ̀ pẹlu a ma mu ẹ̀jẹ, nibiti okú ba gbe wà, nibẹ li on wà pẹlu.

Ka pipe ipin Job 39