Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Job 1:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Oluwa si dá Satani lohùn wipe: kiyesi i, ohun gbogbo ti o ni mbẹ ni ikawọ rẹ, kìki on tikara rẹ̀ ni iwọ kò gbọdọ̀ fi ọwọ rẹ kàn: bẹ̃ni Satani jade lọ kuro niwaju Oluwa.

Ka pipe ipin Job 1

Wo Job 1:12 ni o tọ