Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 9:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si wi fun Joṣua pe, Iranṣẹ rẹ li awa iṣe. Joṣua si wi fun wọn pe, Tali ẹnyin? nibo li ẹnyin si ti wá?

Ka pipe ipin Joṣ 9

Wo Joṣ 9:8 ni o tọ