Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 9:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si da Joṣua lohùn wipe, Nitoriti a sọ fun awọn iranṣẹ rẹ dajudaju, bi OLUWA Ọlọrun rẹ ti paṣẹ fun Mose iranṣẹ rẹ̀, lati fun nyin ni gbogbo ilẹ na, ati lati pa gbogbo awọn ara ilẹ na run kuro niwaju nyin; nitorina awa bẹ̀ru nyin gidigidi nitori ẹmi wa, a si ṣe nkan yi.

Ka pipe ipin Joṣ 9

Wo Joṣ 9:24 ni o tọ