Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 9:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ọmọ Israeli kò pa wọn, nitoriti awọn olori ijọ awọn enia ti fi OLUWA, Ọlọrun Israeli, bura fun wọn. Gbogbo ijọ awọn enia si kùn si awọn olori.

Ka pipe ipin Joṣ 9

Wo Joṣ 9:18 ni o tọ