Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 9:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe, nigbati gbogbo awọn ọba ti mbẹ li apa ihin Jordani, li ori òke, ati li afonifoji, ati ni gbogbo àgbegbe okun nla ti o kọjusi Lebanoni, awọn Hitti, ati awọn Amori, awọn Kenaani, awọn Perissi, awọn Hifi, ati awọn Jebusi, gbọ́ ọ;

Ka pipe ipin Joṣ 9

Wo Joṣ 9:1 ni o tọ