Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 8:31 Yorùbá Bibeli (YCE)

Gẹgẹ bi Mose iranṣẹ OLUWA ti paṣẹ fun awọn ọmọ Israeli, gẹgẹ bi a ti kọ ọ ninu iwé ofin Mose, pẹpẹ odidi okuta, lara eyiti ẹnikan kò fi irin kan: nwọn si ru ẹbọ sisun lori rẹ̀ si OLUWA, nwọn si ru ẹbọ alafia.

Ka pipe ipin Joṣ 8

Wo Joṣ 8:31 ni o tọ