Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 8:29 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọba Ai li o si so rọ̀ lori igi titi di aṣalẹ: bi õrùn si ti wọ̀, Joṣua paṣẹ ki a sọ okú rẹ̀ kuro lori igi kalẹ, ki a si wọ́ ọ jù si atiwọ̀ ibode ilu na, ki a si kó òkiti nla okuta lé e lori, ti mbẹ nibẹ̀ titi di oni-oloni.

Ka pipe ipin Joṣ 8

Wo Joṣ 8:29 ni o tọ