Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 8:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe, gbogbo awọn ti o ṣubu ni ijọ́ na, ati ọkunrin ati obinrin, jẹ́ ẹgba mẹfa, ani gbogbo ọkunrin Ai.

Ka pipe ipin Joṣ 8

Wo Joṣ 8:25 ni o tọ