Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 8:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iwọ o si ṣe si Ai ati si ọba rẹ̀ gẹgẹ bi iwọ ti ṣe si Jeriko ati si ọba rẹ̀: kìki ikogun rẹ̀, ati ohun-ọ̀sin rẹ̀, li ẹnyin o mú ni ikogun fun ara nyin: rán enia lọ iba lẹhin ilu na.

Ka pipe ipin Joṣ 8

Wo Joṣ 8:2 ni o tọ