Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 7:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati mo ri ẹ̀wu Babeli kan daradara ninu ikogun, ati igba ṣekeli fadakà, ati dindi wurà kan oloṣuwọn ãdọta ṣekeli, mo ṣojukokoro wọn, mo si mú wọn; sawò o, a fi wọn pamọ́ ni ilẹ lãrin agọ́ mi, ati fadakà na labẹ rẹ̀.

Ka pipe ipin Joṣ 7

Wo Joṣ 7:21 ni o tọ