Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 7:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Yio si ṣe, ẹniti a ba mú pẹlu ohun ìyasọtọ na, a o fi iná sun u, on ati ohun gbogbo ti o ní: nitoriti o rú ofin OLUWA, ati nitoriti o si hù ìwakiwa ni Israeli.

Ka pipe ipin Joṣ 7

Wo Joṣ 7:15 ni o tọ