Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 6:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Yio si ṣe, nigbati nwọn ba fọn ipè jubeli kikan, nigbati ẹnyin ba si gbọ́ iró ipè na, gbogbo awọn enia yio si hó kũ; odi ilu na yio si wó lulẹ, bẹrẹ, awọn enia yio si gòke lọ tàra, olukuluku niwaju rẹ̀.

Ka pipe ipin Joṣ 6

Wo Joṣ 6:5 ni o tọ