Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 6:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹnyin o si ká ilu na mọ́, gbogbo ẹnyin ologun, ẹnyin o si yi ilu na ká lẹ̃kan. Bayi ni iwọ o ṣe ni ijọ́ mẹfa.

Ka pipe ipin Joṣ 6

Wo Joṣ 6:3 ni o tọ