Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 6:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ilu na yio si jẹ́ ìyasọtọ si OLUWA, on ati gbogbo ohun ti mbẹ ninu rẹ̀: kìki Rahabu panṣaga ni yio là, on ati gbogbo awọn ti mbẹ ni ile pẹlu rẹ̀, nitoriti o pa awọn onṣẹ ti a rán mọ́.

Ka pipe ipin Joṣ 6

Wo Joṣ 6:17 ni o tọ