Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 6:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Joṣua si paṣẹ fun awọn enia wipe, Ẹ kò gbọdọ hó bẹ̃li ẹ kò gbọdọ pariwo, bẹ̃li ọ̀rọ kan kò gbọdọ jade li ẹnu nyin, titi ọjọ́ ti emi o wi fun nyin pe, ẹ hó; nigbana li ẹnyin o hó.

Ka pipe ipin Joṣ 6

Wo Joṣ 6:10 ni o tọ