Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 5:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Idí rẹ̀ li eyi ti Joṣua fi kọ wọn nilà: gbogbo awọn enia ti o ti Egipti jade wá, ti o ṣe ọkunrin, ani gbogbo awọn ọmọ-ogun, nwọn kú li aginjù, li ọ̀na, lẹhin igbati nwọn jade kuro ni Egipti.

Ka pipe ipin Joṣ 5

Wo Joṣ 5:4 ni o tọ