Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 4:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitoriti OLUWA Ọlọrun nyin mu omi Jordani gbẹ kuro niwaju nyin, titi ẹnyin fi là a kọja, gẹgẹ bi OLUWA Ọlọrun nyin ti ṣe si Okun Pupa, ti o mu gbẹ kuro niwaju wa, titi awa fi là a kọja:

Ka pipe ipin Joṣ 4

Wo Joṣ 4:23 ni o tọ