Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 4:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe, nigbati awọn alufa ti o rù apoti majẹmu OLUWA ti ãrin Jordani jade, ti awọn alufa si gbé atẹlẹsẹ̀ wọn soke si ilẹ gbigbẹ, ni omi Jordani pada si ipò rẹ̀, o si ṣàn bò gbogbo bèbe rẹ̀, gẹgẹ bi ti iṣaju.

Ka pipe ipin Joṣ 4

Wo Joṣ 4:18 ni o tọ