Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 4:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Li ọjọ́ na OLUWA gbé Joṣua ga li oju gbogbo Israeli: nwọn si bẹ̀ru rẹ̀, gẹgẹ bi nwọn ti bẹ̀ru Mose li ọjọ́ aiye rẹ̀ gbogbo.

Ka pipe ipin Joṣ 4

Wo Joṣ 4:14 ni o tọ