Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 4:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. O si ṣe, nigbati gbogbo awọn enia rekọja Jordani tán, ni OLUWA wi fun Joṣua pe,

2. Mú ọkunrin mejila ninu awọn enia, ọkunrin kan ninu olukuluku ẹ̀ya,

Ka pipe ipin Joṣ 4