Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 24:32 Yorùbá Bibeli (YCE)

Egungun Josefu, ti awọn ọmọ Israeli gbé gòke lati Egipti wá, ni nwọn si sin ni Ṣekemu, ni ipín ilẹ ti Jakobu rà lọwọ awọn ọmọ Hamori baba Ṣekemu li ọgọrun owo: o si di ilẹ-iní awọn ọmọ Josefu.

Ka pipe ipin Joṣ 24

Wo Joṣ 24:32 ni o tọ