Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 24:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi o ba si ṣe buburu li oju nyin lati sìn OLUWA, ẹ yàn ẹniti ẹnyin o ma sìn li oni; bi oriṣa wọnni ni ti awọn baba nyin ti o wà ni ìha keji Odò ti nsìn, tabi awọn oriṣa awọn Amori, ni ilẹ ẹniti ẹnyin ngbé: ṣugbọn bi o ṣe ti emi ati ile mi ni, OLUWA li awa o ma sìn.

Ka pipe ipin Joṣ 24

Wo Joṣ 24:15 ni o tọ