Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 24:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi si fun nyin ni ilẹ ti iwọ kò ṣe lãla si, ati ilu ti ẹnyin kò tẹ̀dó, ẹnyin si ngbé inu wọn; ninu ọgbà-àjara ati ọgbà-igi-olifi ti ẹnyin kò gbìn li ẹnyin njẹ.

Ka pipe ipin Joṣ 24

Wo Joṣ 24:13 ni o tọ