Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 23:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe li ọjọ́ pipọ̀ lẹhin ti OLUWA ti fi isimi fun Israeli lọwọ gbogbo awọn ọtá wọn yiká, ti Joṣua di arugbó, ti o si pọ̀ li ọjọ́;

Ka pipe ipin Joṣ 23

Wo Joṣ 23:1 ni o tọ