Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 22:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ọmọ Reubeni, ati awọn ọmọ Gadi, ati àbọ ẹ̀ya Manasse si pada, nwọn si lọ kuro lọdọ awọn ọmọ Israeli lati Ṣilo, ti mbẹ ni ilẹ Kenaani, lati lọ si ilẹ Gileadi, si ilẹ iní wọn, eyiti nwọn ti gbà, gẹgẹ bi aṣẹ OLUWA lati ọwọ́ Mose wá.

Ka pipe ipin Joṣ 22

Wo Joṣ 22:9 ni o tọ