Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 22:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Njẹ fun àbọ ẹ̀ya Manasse ni Mose ti fi ilẹ-iní wọn fun ni Baṣani: ṣugbọn fun àbọ ẹ̀ya ti o kù ni Joṣua fi ilẹ-iní fun pẹlu awọn arakunrin wọn ni ìha ihin Jordani ni ìwọ-õrùn. Nigbati Joṣua si rán wọn pada lọ sinu agọ́ wọn, o sure fun wọn pẹlu,

Ka pipe ipin Joṣ 22

Wo Joṣ 22:7 ni o tọ