Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 22:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Njẹ nisisiyi OLUWA Ọlọrun nyin ti fi isimi fun awọn arakunrin nyin, gẹgẹ bi o ti sọ fun wọn: njẹ nisisiyi ẹ pada, ki ẹ si lọ sinu agọ́ nyin, ati si ilẹ-iní nyin, ti Mose iranṣẹ OLUWA ti fun nyin ni ìha keji Jordani.

Ka pipe ipin Joṣ 22

Wo Joṣ 22:4 ni o tọ