Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 22:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bayi ni gbogbo ijọ OLUWA wi, Ẹ̀ṣẹ kili eyiti ẹnyin da si Ọlọrun Israeli, lati pada li oni kuro lẹhin OLUWA, li eyiti ẹnyin mọ pẹpẹ kan fun ara nyin, ki ẹnyin ki o le ṣọ̀tẹ si OLUWA li oni?

Ka pipe ipin Joṣ 22

Wo Joṣ 22:16 ni o tọ