Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 21:38 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati ninu ẹ̀ya Gadi, Ramotu ni Gileadi pẹlu àgbegbe rẹ̀, ilu àbo fun apania; ati Mahanaimu pẹlu àgbegbe rẹ̀.

Ka pipe ipin Joṣ 21

Wo Joṣ 21:38 ni o tọ