Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 21:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati awọn ọmọ Gerṣoni, idile awọn ọmọ Lefi, ni nwọn fi Golani ni Baṣani fun pẹlu àgbegbe rẹ̀, ilu àbo fun apania; lati inu ẹ̀ya Manasse, ati Be-eṣtera pẹlu àgbegbe rẹ̀; ilu meji.

Ka pipe ipin Joṣ 21

Wo Joṣ 21:27 ni o tọ