Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 2:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si wi fun awọn ọkunrin na pe, Emi mọ̀ pe OLUWA ti fun nyin ni ilẹ yi, ati pe ẹ̀ru nyin bà ni, ati pe ọkàn gbogbo awọn ara ilẹ yi di omi nitori nyin.

Ka pipe ipin Joṣ 2

Wo Joṣ 2:9 ni o tọ