Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 2:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si lọ, nwọn si dé ori òke, nwọn si gbé ibẹ̀ ni ijọ́ mẹta, titi awọn alepa fi pada: awọn alepa wá wọn ni gbogbo ọ̀na, ṣugbọn nwọn kò ri wọn.

Ka pipe ipin Joṣ 2

Wo Joṣ 2:22 ni o tọ