Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 2:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Kiyesi i, nigbati awa ba dé inu ilẹ na, iwọ o so okùn owú ododó yi si oju-ferese ti iwọ fi sọ̀ wa kalẹ: iwọ o si mú baba rẹ, ati iya rẹ, ati awọn arakunrin rẹ, ati gbogbo ara ile baba rẹ, wá ile sọdọ rẹ.

Ka pipe ipin Joṣ 2

Wo Joṣ 2:18 ni o tọ