Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 2:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si wi fun wọn pe, Ẹ bọ sori òke, ki awọn alepa ki o má ba le nyin bá; ki ẹnyin si fara nyin pamọ́ nibẹ̀ ni ijọ́ mẹta, titi awọn alepa yio fi pada: lẹhin na ẹ ma ba ọ̀na ti nyin lọ.

Ka pipe ipin Joṣ 2

Wo Joṣ 2:16 ni o tọ