Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 2:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ọkunrin na da a lohùn pe, Ẹmi wa ni yio dipò ti nyin, bi ẹnyin kò ba fi ọ̀ran wa yi hàn; yio si ṣe, nigbati OLUWA ba fun wa ni ilẹ na, awa o ṣe ore ati otitọ fun ọ.

Ka pipe ipin Joṣ 2

Wo Joṣ 2:14 ni o tọ