Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 18:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹ yàn ọkunrin mẹta fun ẹ̀ya kọkan: emi o si rán wọn, nwọn o si dide, nwọn o si là ilẹ na já, nwọn o si ṣe apejuwe rẹ̀ gẹgẹ bi ilẹ-iní wọn; ki nwọn ki o si pada tọ̀ mi wá.

Ka pipe ipin Joṣ 18

Wo Joṣ 18:4 ni o tọ